1 Chronicles 2
World English Bible (en) → Yoruba Contemporary Bible (Biblica) (yo)
- 1
Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Israẹli. Reubeni, Simeoni, Lefi, Juda, Isakari, Sebuluni,
- 2
Dani, Josẹfu, Benjamini; Naftali, Gadi: àti Aṣeri.
- 3
Àwọn ọmọ Juda:
- 4
Tamari, aya ọmọbìnrin Juda, ó sì bí Peresi àti Sera sì ní ọmọ márùn-ún ní àpapọ̀.
- 5
Àwọn ọmọ Peresi:
- 6
Àwọn ọmọ Sera:
- 7
Àwọn ọmọ Karmi:
- 8
Àwọn ọmọ Etani:
- 9
Àwọn ọmọ tí a bí fún Hesroni ni:
- 10
Ramu sì ni baba Amminadabu,
- 11
Nahiṣoni sì ni baba Salmoni,
- 12
Boasi baba Obedi
- 13
Jese sì ni baba
- 14
ẹlẹ́ẹ̀kẹrin Netaneli,
- 15
ẹlẹ́ẹ̀kẹfà Osemu
- 16
Àwọn arábìnrin wọn ni Seruiah àti Abigaili.
- 17
Abigaili ni ìyá Amasa, ẹni tí baba rẹ̀ sì jẹ́ Jeteri ará Iṣmaeli.
- 18
Kalebu ọmọ Hesroni ní ọmọ láti ọ̀dọ̀ ìyàwó rẹ̀ Asuba (láti ọ̀dọ̀ Jerioti). Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ rẹ̀:
- 19
Nígbà tí Asuba sì kú, Kalebu sì fẹ́ Efrata ní aya, ẹni tí ó bí Huri fún un.
- 20
Huri ni baba Uri, Uri sì jẹ́ baba Besaleli.
- 21
Nígbà tí ó yá, Hesroni sì dùbúlẹ̀ pẹ̀lú ọmọbìnrin Makiri baba Gileadi (ó sì ti fẹ́ ní aya láti ìgbà tí ó ti wà ní ẹni ọgọ́ta ọdún) ó sì bí Segubu.
- 22
Segubu sì jẹ́ baba Jairi, ẹni tí ó jẹ́ olùdarí ìlú mẹ́tàlélógún ní ilẹ̀ Gileadi.
- 23
(Ṣùgbọ́n Geṣuri àti Aramu sì fi agbára gba Hafoti-Jairi, àti Kenati pẹ̀lú gbogbo agbègbè rẹ̀ tí wọn tẹ̀dó sí jẹ́ ọgọ́ta ìlú.)
- 24
Lẹ́yìn tí Hesroni sì kú ni Kalebu Efrata, Abijah ìyàwó rẹ̀ ti Hesroni sì bí Aṣihuri baba Tekoa fún un.
- 25
Ọmọ Jerahmeeli àkọ́bí Hesroni:
- 26
Jerahmeeli ní ìyàwó mìíràn, ẹni tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Atara; ó sì jẹ́ ìyá fún Onamu.
- 27
Àwọn ọmọ Ramu àkọ́bí Jerahmeeli:
- 28
Àwọn ọmọ Onamu:
- 29
Orúkọ ìyàwó Abiṣuri ni Abihaili ẹni tí ó bí Ahbani àti Molidi.
- 30
Àwọn ọmọ Nadabu
- 31
Àwọn ọmọ Appaimu:
- 32
Àwọn ọmọ Jada, arákùnrin Ṣammai:
- 33
Àwọn ọmọ Jonatani:
- 34
Ṣeṣani kò sì ní ọmọkùnrin àwọn ọmọbìnrin nìkan ni ó ní.
- 35
Ṣeṣani sì fi ọmọ obìnrin rẹ̀ ní aya fún ìránṣẹ́ rẹ̀ Jariha, ó sì bí ọmọ fún tí orúkọ rẹ̀ jẹ́ Attai.
- 36
Attai sì jẹ́ baba fún Natani,
- 37
Sabadi ni baba Eflali,
- 38
Obedi sì ni baba Jehu,
- 39
Asariah sì ni baba Helesi,
- 40
Eleasa ni baba Sismai,
- 41
Ṣallumu sì ni baba Jekamiah,
- 42
Àwọn ọmọ Kalebu arákùnrin Jerahmeeli:
- 43
Àwọn ọmọ Hebroni:
- 44
Ṣema ni baba Rahamu,
- 45
Àwọn ọmọ Ṣammai ni Maoni,
- 46
Efani obìnrin Kalebu sì ni ìyá
- 47
Àwọn ọmọ Jahdai:
- 48
Maaka obìnrin Kalebu sì ni ìyá
- 49
Ó sì bí Ṣaafu baba Madmana,
- 50
Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Kalebu.
- 51
Salma baba Bẹtilẹhẹmu àti Harefu baba Beti-Gaderi.
- 52
Àwọn ọmọ Ṣobali baba Kiriati-Jearimu ni:
- 53
Àti ìdílé Kiriati-Jearimu: àti àwọn ara Itri, àti àwọn ará Puti, àti àwọn ará Ṣumati àti àwọn ará Miṣraiti: láti ọ̀dọ̀ wọn ni àwọn ọmọ ará Sorati àti àwọn ará Eṣtaoli ti wá.
- 54
Àwọn ọmọ Salma:
- 55
àti àwọn ìdílé àwọn akọ̀wé, ẹni tí ń gbé ní Jabesi: àti àwọn ọmọ Tirati àti àwọn ará Ṣimeati àti àwọn ará Sukati. Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ará Keni, ẹni tí ó wá láti ọ̀dọ̀ Hamati, baba ilé Rekabu.