1 Chronicles 1
World English Bible (en) → Yoruba Contemporary Bible (Biblica) (yo)
- 1
Adamu, Seti, Enoṣi,
- 2
Kenani, Mahalaleli, Jaredi,
- 3
Enoku, Metusela, Lameki,
- 4
Àwọn ọmọ Noa: Ṣemu, Hamu àti Jafeti.
- 5
Àwọn ọmọ Jafeti ni:
- 6
Àwọn ọmọ Gomeri ni:
- 7
Àwọn ọmọ Jafani ni:
- 8
Àwọn ọmọ Hamu ni:
- 9
Àwọn ọmọ Kuṣi ni:
- 10
Kuṣi sì bí Nimrodu
- 11
Ejibiti sì bí
- 12
Patrusimu, Kasluhimu (láti ọ̀dọ̀ ẹni tí àwọn ará Filistini ti wá) àti àwọn ará Kaftorimu.
- 13
Kenaani sì bí Sidoni àkọ́bí rẹ̀,
- 14
àti àwọn ará Jebusi, àti àwọn ará Amori, àti àwọn ará Girgaṣi,
- 15
àti àwọn ará Hifi, àti àwọn ará Arki, àti àwọn ará Sini,
- 16
àti àwọn ará Arfadi, àti àwọn ará Semari, àti àwọn ará Hamati.
- 17
Àwọn ọmọ Ṣemu ni:
- 18
Arfakṣadi sì bí Ṣela,
- 19
Eberi sì bí ọmọ méjì:
- 20
Joktani sì bí
- 21
Hadoramu, Usali, Dikla,
- 22
Ebali, Abimaeli, Ṣeba.
- 23
Ofiri, Hafila, àti Jobabu. Gbogbo àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Joktani.
- 24
Ṣemu, Arfakṣadi, Ṣela,
- 25
Eberi, Pelegi. Reu,
- 26
Serugu, Nahori, Tẹra,
- 27
àti Abramu (tí ń ṣe Abrahamu).
- 28
Àwọn ọmọ Abrahamu: Isaaki àti Iṣmaeli.
- 29
Èyí ni àwọn ọmọ náà:
- 30
Miṣima, Duma, Massa, Hadadi, Tema,
- 31
Jeturi, Nafiṣi, àti Kedema.
- 32
Àwọn ọmọ Ketura, obìnrin Abrahamu:
- 33
Àwọn ọmọ Midiani:
- 34
Abrahamu sì jẹ́ baba Isaaki.
- 35
Àwọn ọmọ Esau:
- 36
Àwọn ọmọ Elifasi:
- 37
Àwọn ọmọ Reueli:
- 38
Àwọn ọmọ Seiri:
- 39
Àwọn ọmọ Lotani:
- 40
Àwọn ọmọ Ṣobali:
- 41
Àwọn ọmọ Ana:
- 42
Àwọn ọmọ Eseri:
- 43
Àwọn wọ̀nyí ni ọba tí ó jẹ ní Edomu, kí ó tó di pé ọba kankan jẹ lórí Israẹli:
- 44
Nígbà tí Bela kú, Jobabu ọmọ Sera ti Bosra sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.
- 45
Nígbà tí Jobabu kú, Huṣamu láti ilẹ̀ Temani sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.
- 46
Nígbà tí Huṣamu kú, Hadadi ọmọ Bedadi tí ó kọlu Midiani ní ìgbẹ́ Moabu, ó sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Orúkọ ìlú rẹ̀ ni Afiti.
- 47
Nígbà tí Hadadi sì kú, Samla láti Masreka, ó sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.
- 48
Samla sì kú, Saulu ti Rehoboti létí odò sì jẹ ọba ní ipò rẹ̀.
- 49
Nígbà tí Saulu kú, Baali-Hanani, ọmọ Akbori jẹ ọba ní ipò rẹ̀.
- 50
Nígbà tí Baali-Hanani kú, Hadadi ni ó jẹ ọba ní ipò rẹ̀. Orúkọ ìlú rẹ̀ ni Pau; orúkọ ìyàwó sì ni Mehetabeeli ọmọbìnrin Matiredi, ọmọbìnrin Mesahabu.
- 51
Hadadi sì kú pẹ̀lú.
- 52
baálẹ̀ Oholibama, baálẹ̀ Ela, baálẹ̀ Pinoni.
- 53
Baálẹ̀ Kenasi, baálẹ̀ Temani, baálẹ̀ Mibsari,
- 54
Magdieli àti Iramu.