1 Chronicles 3
World English Bible (en) → Yoruba Contemporary Bible (Biblica) (yo)
- 1
Àwọn wọ̀nyí sì ni ọmọ Dafidi tí a bí fún un ní Hebroni.
- 2
ẹ̀kẹta sì ni Absalomu ọmọ Maaka ọmọbìnrin Talmai ọba Geṣuri bí fún un;
- 3
ẹ̀karùnún ni Ṣefatia láti ọ̀dọ̀ Abitali;
- 4
Àwọn mẹ́fà wọ̀nyí ni a bí fún Dafidi ni Hebroni, níbi tí ó ti jẹ ọba fún ọdún méje àti oṣù mẹ́fà.
- 5
Wọ̀nyí ni ọmọ wẹ́wẹ́ tí a bí fún un ní Jerusalẹmu:
- 6
Ibhari sì wà pẹ̀lú, Eliṣama, Elifeleti,
- 7
Noga, Nefegi, Jafia,
- 8
Eliṣama, Eliada àti Elifeleti mẹ́sàn-án ni wọ́n.
- 9
Àwọn wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Dafidi yàtọ̀ sí àwọn ọmọ tí àlè bí fún un. Tamari sì ni arábìnrin wọn.
- 10
Ọmọ Solomoni ni Rehoboamu,
- 11
Jehoramu ọmọ rẹ̀,
- 12
Amasiah ọmọ rẹ̀,
- 13
Ahasi ọmọ rẹ̀,
- 14
Amoni ọmọ rẹ̀,
- 15
Àwọn ọmọ Josiah:
- 16
Àwọn ìran ọmọ Jehoiakimu:
- 17
Àwọn ọmọ Jekoniah tí a mú ní ìgbèkùn:
- 18
Malkiramu, Pedaiah, Ṣenasari, Jekamiah, Hoṣama àti Nedabiah.
- 19
Àwọn ọmọ Pedaiah:
- 20
Àwọn márùn-ún mìíràn sì tún wà: Haṣuba, Oheli, Berekiah, Hasadiah àti Jusabhesedi.
- 21
Àwọn ọmọ Hananiah:
- 22
Àwọn ọmọ Ṣekaniah:
- 23
Àwọn ọmọ Neariah:
- 24
Àwọn ọmọ Elioenai: