1 Chronicles 8
World English Bible (en) → Yoruba Contemporary Bible (Biblica) (yo)
- 1
Benjamini jẹ́ baba:
- 2
Noha ẹ̀ẹ̀kẹrin àti Rafa ẹ̀karùnún.
- 3
Àwọn ọmọ Bela ni,
- 4
Abiṣua, Naamani, Ahoa,
- 5
Gera, Ṣefufani àti Huramu.
- 6
Wọ̀nyí ni àwọn ìran ọmọ Ehudu, tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé tí ó ń gbé ní Geba tí a sì lé kúrò lọ sí Manahati:
- 7
Naamani Ahijah àti Gera, tí ó lé wọn kúrò ní ìlú, àti tí ó sì jẹ́ baba Ussa àti Ahihudu.
- 8
A bí àwọn ọmọkùnrin fún Ṣaharaimu ní Moabu lẹ́yìn tí ó ti kọ àwọn ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀, Huṣimu àti Baara.
- 9
Nípasẹ̀ ìyàwó rẹ̀ Hodeṣi ó ní Jobabu Sibia, Meṣa, Malkamu,
- 10
Jeusi, Sakia àti Mirma. Wọ̀nyí ni àwọn ọmọkùnrin rẹ̀, olórí àwọn ìdílé.
- 11
Nípasẹ̀ Huṣimu ó ní Abitubu àti Elipali.
- 12
Àwọn ọmọ Elipali:
- 13
Pẹ̀lú Beriah àti Ṣema, tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé ti àwọn tí ó ń gbé ní Aijaloni àti àwọn tí ó lé àwọn olùgbé Gati kúrò.
- 14
Ahio, Ṣasaki, Jeremoti,
- 15
Sebadiah, Aradi, Ederi
- 16
Mikaeli, Iṣifa àti Joha jẹ́ àwọn ọmọ Beriah.
- 17
Sebadiah, Meṣullamu, Hiski, Heberi
- 18
Iṣimerai, Isiliahi àti Jobabu jẹ́ àwọn ọmọ Elipali.
- 19
Jakimu, Sikri, Sabdi,
- 20
Elienai, Siletai, Elieli,
- 21
Adaiah, Beraiah àti Ṣimrati jẹ́ àwọn ọmọ, Ṣimei.
- 22
Iṣipani Eberi, Elieli,
- 23
Abdoni, Sikri, Hanani,
- 24
Hananiah, Elamu, Anitotijah,
- 25
Ifediah àti Penueli jẹ́ àwọn ọmọ Ṣasaki.
- 26
Ṣamṣerai, Ṣeharaiah, Ataliah
- 27
Jareṣiah, Elijah àti Sikri jẹ́ àwọn ọmọ Jerohamu.
- 28
Gbogbo àwọn wọ̀nyí jẹ́ olórí àwọn ìdílé, olóyè gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ lẹ́sẹẹsẹ nínú ìtàn ìran wọn, wọ́n sì ń gbé ní Jerusalẹmu.
- 29
Jeieli, baba Gibeoni ń gbé ní Gibeoni.
- 30
àkọ́bí rẹ̀ a sì máa jẹ́ Abdoni wọ̀nyí sì ń tẹ̀lé Suri, Kiṣi, Baali, Neri, Nadabu,
- 31
Gedori Ahio, Sekeri
- 32
pẹ̀lú Mikiloti, tí ó jẹ́ baba Ṣimea. Wọ́n ń gbé ní ẹ̀bá ìbátan wọn ní Jerusalẹmu.
- 33
Neri jẹ́ baba Kiṣi, Kiṣi baba Saulu àti Saulu baba Jonatani, Malikiṣua, Abinadabu àti Eṣi-Baali.
- 34
Ọmọ Jonatani:
- 35
Àwọn ọmọ Mika:
- 36
Ahasi jẹ́ baba a Jeheada, Jeheada jẹ́ baba a Alemeti, Asmafeti àti Simri, Simri sì jẹ́ baba Mosa.
- 37
Mosa jẹ́ baba Binea; Rafa sì jẹ́ ọmọ rẹ̀, Eleasa ọmọ rẹ̀ àti Aseli ọmọ rẹ̀.
- 38
Aseli ní ọmọ mẹ́fà pẹ̀lú wọ̀nyí ni orúkọ wọn:
- 39
Àwọn ọmọ arákùnrin rẹ̀ Eseki:
- 40
Àwọn ọmọ Ulamu jẹ́ ògboyà jagunjagun tí ó lè gbá orin mú. Wọ́n ní ọ̀pọ̀ ọmọkùnrin àti ọmọ ọmọkùnrin áàdọ́jọ ní gbogbo rẹ̀.